
Sunday Igboho: Aráalé kan ní DSS fo ògiri wọ́lé ní nígbà tí wọn kò rí ìlẹ̀kùn já
Ọkan lara awọn eniyan to wa ni ile Sunday Igboho, to fi orukọ bo ara rẹ lasiri ti salaye ohun to sẹlẹ nigba ti awọn ikọ otẹlẹmuyẹ DSS ṣekọlu si ile Sunday Igboho ni ooru ọjọ naa. Ẹni naa to ba ileeṣẹ iroyin Cable sọrọ wi pe, awọn to ṣe ikọlu naa wo aṣọ ologun…