
Wọn yan akọroyin Gbelegbọ awọọdu akọroyin to lami-laka fun ami-ẹyẹ YOMAFA ọdun yii
Awọn akọroyin Gbelegbọ meji, Taofik Afọlabi ati Kayọde Ọmọtọṣọ wa ninu awọn akọroyin ti wọn yan gẹgẹ bii akọroyin to lami-laka ju lọ fun ọdun 2020 ati 2021 fun ami-ẹyẹ YOMAFA. Awọn akọroyin Gbelebọ yii wa ninu awọn oniroyin ti wọn lami-laka ti ajọ YOMAFA yan fun ami-ẹyẹ akọroyin to dara ju lọ. Ọjọ kin…