
Asiiri Nla: Lẹyin to bimọ tuntun tan, Liz Anjọrin ni ibẹfa lo wu mi ki n tun bi
Gbajugbaja oṣere tiata wa, to tun jẹ oniṣowo pataki, Alaaja Aishat Elizabeth Lawal ti gbogbo aye mọ si Liz Anjọrin ti sọ pe ibẹfa lo wu oun bi lẹyin ọmọ tuntun toun ṣẹṣẹ bi yii, bẹẹ lo fidi ẹ mulẹ pe oun ko fẹ ki kinni ọhun pẹ rara. Oṣere nla yii ti awọn eeyan…