
Funmi Awelewa – N kò ní gbà kẹ lò mí tán, kẹ wá já mi jù sílẹ̀ bíi náírà márùn-ún àlòkù
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn olólùfẹ́ Orijafunmi Awelewa, lọ tí ń janu lójú òpó Instagram láti gbé sẹ́yìn gbajúgbajà òṣèré olólùfẹ́ wọn, tó sọ̀kò ọ̀rọ̀ lu àwọn akẹ́gbẹ́ rẹ̀. Àwọn akẹẹgbẹ́ rẹ̀ yìí ló ní wọ́n fẹ́ràn láti má sanwó iṣẹ́ tí wọ́n bá bẹ akẹ́gbẹ́ wọ́n láti kópa nínú sinimá agbéléwò. Gẹ́gẹ́ bí ó ṣe kọ́ soju…