
Sunday Igboho: Elebuibon ní kìí ṣe pé ewé sunko fún Sunday Igboho, ìjàmbá làwọn DSS ṣe fún un
Oloye Sunday Adeyemo ti ọpọ mọ si Sunday Igboho jẹ ẹnikan ti ọpọ n wo gẹgẹ bi alagbara to kaato lati gbawọn eeyan silẹ lọwọ awọn afiya jẹni. Idi niyii ti wọn maa fi n pe ni Igboho Oosa, ajijagbara ati ajafẹtọ ọmọniyan. Eyi gan an lo jẹ ko wa lara awọn to n ṣe…