Ẹ̀ṣọ́ Amotekun nawọ́ gán afurasí ajínigbé 43 ní ìpínlẹ̀ Ondo
Ẹ̀ṣọ́ ààbò Amotekun ní ìpínlẹ̀ Ondo ti nawọ́ gán àwọn afurasí mẹ́tàlélógójì fún ìwà ọ̀daràn lọ́kan-ò-jọ̀kan káàkiri ìjọb aìbílẹ̀ méjìdínlógún ní ìpínlẹ̀ náà. Èyí ló ń wáyé lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́rin tí àwọn kan jí àwọn ènìyàn kan gbé nínú ọkọ̀ bọ́ọ̀sì kan, tí wọ́n sì pa awakọ̀ ọ̀hún ní òpópónà Akunnu Ayere tó wà ní…

