Radio Nigeria attack: Àwọn jàndùkú ba ọ̀kẹ́ àìmoye dúkìá jẹ́ lásìkò ìkọlù síAmuludun FM n’Ibadan
Ọkan lara awọn oṣiṣẹ ileeṣẹ naa sọ fun BBC Yoruba pe ọpọ dukia ti iye rẹ ko din ni ọpọ miliọnu naira ni awọn janduku ọhun bajẹ lasiko ikọlu naa. Lara awọn ohun ti wọn bajẹ ni awọn irinṣẹ ti wọn n lo ni ọọfisi, awọn ferese ọọfisi, to fi mọ awọn ọkọ ayọkẹlẹ atawọn…

