Traditionalist Oba Ogun: Àwọn oníṣẹ̀ṣe ń fẹ́ kí ìjọba yọ ọwọ́ nínú Ọba yíyàn ní ìpínlẹ̀ Ogun
Wọn ni ki awọn aṣofin ọhun dawọ iṣẹ duro lori abadofin naa ti yoo fun ijọba lagbara lati maa ṣakoso bi wọn ṣe yan ọba nitori kii ṣe iṣẹ wọn. Agbẹnusọ awọn oniṣẹṣe nipinlẹ ogun, Ifayemi Osunlabi sọ fun awọn akọroyin niluu Abeokuta pe ti abadofin naa ba le di ofin, yoo pa awọn etutu…

